[ Featuring Ayọmidé Africa ]
Toolz bámi yí mic yẹn sókè
They call me Africa
I mount my guard mo dúró kampe
Make I no lose my steeze my composure
Temperature don rise Orí mi gbóná feli feli
Omo anyhow e be
Wetin go be go be
Kòsóun tóun bọ̀ lókè tílè ò nígbà
This life na rollacoster ah agh ahn
The pain no go last forever
Whatever the matter
E go better ah agh ah
You no go sad forever
No too dey bother
Ayewada ah agh ah
Ah ó kàn ń shọmọ Olóòkú bẹẹni bẹẹni bẹẹni
Ó kàn ń shọmọ Olóòkú bẹẹni bẹẹni bẹẹni
Ó kàn ń shọmọ Olóòkú bẹẹni bẹẹni bẹẹni
(Ah ahn ahn ahn ahn ahn ahn ah)
Ìwà Ọmọ ló ún Mọmọ shòkígbẹ́
Àìrìnjìnà laà rábuké ọ̀kérẹ́
Abẹ́reẹ́ á lo kọ́nà okùn ótódí
E go shock them high tension wire (Agh hu)
Wọ́n máa ganu ti n bá gba wire
Ah wi ah
Ẹ fọ̀wọ̀ mi wọ̀mí
Èmi lọmọ Ọlọ́wọ̀ Madẹ̀
(Hmm Toolz lo Shey beat yi Ah)
Pain no go last forever
No matter the weather
E go better ahn ahn ahn
(Ayọmide you bhad I swear)
Lori ta mẹtta